Lyrics

Qdot – Emi Lo Kan Lyrics

Qdot Emi Lo Kan Lyrics

Omo mo moriamo
2t upon the beat
Qdot lorukomi
Kuronbeyen na
Oshe kini olule
Oshe keji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se

Karin (emilokan)
Egbe kiniyi wa (emilokan)
Kiniyi kini mi ni (emilokan)
Angeli ton pinre (emilokan)
Pinre kanmi (emilokan)
Mogbodo lowo (emilokan)
Omolorun ogbodo shesho (emilokan)
I
re owo (emilokan)
Ire omo (emilokan)
Alubarika (emilokan)
London wo inu America (emilokan)
Dubai wo canada (emilokan)
Bai lase ko oro mhi (emilokan)
Iran meta ogbodo to loshi (emilokan)
Korimi dori owo (emilokan)
Korimi dori apesin (emilokan)
All I need is blessing (emilokan)

Oshe kini lule
Oshekeji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se ikerin( emilokan)
Odun yi odun mhi ni (emilokan)
Orimi ma ja mi kun le (emilokan)
Olorun Ona wa mimo Olorun asakiatu
Maleka waloda (emilokan)
Kaye mabimi pe olorun mi da (emilokan)

Awon elenu shor shor shor (emilokan)
Awon elenu sho sho sho (emilokan)
Won a dema sosokuso (emiloka)
Wo ola bibeli re (emilokan)
Wo ola kurani re (emilokan)
Wo la kini awon baba mi kan ton dun woro woro
Baba maje n pofo (emilokan)
Ki ye fori olori toro (emilokan)

Oshe kini olule
Oshe keji lule
Oshe keta lule
Edakun ema je ko se Karin (emilokan)
Igba mi lode (emilokan)
Omo moriamo fe gbade (emilokan)
Eso fun sunny alade (emilokan)
Oro te ba so fun sango o (emilokan)
Sango ma so f’oya (emilokan)
Eso fun dangote (emilokan)
Pe ko so f okoya (emilokan)
Emi na fe ma shanu eniyan bi ti

Dende nilaro Mc fo wo yemisi (emilokan)
Mo mo rilwan cooler eyan paso (emilokan)
Alagbe ton fun alagbe lowo (emilokan)
Arowolo lo n ta motor (emilokan)
Dr brown (emilokan)
Lanre typical (emilokan)
Ti ba ni uhmm uhmm (emilokan)
Tiba ni ehen ehen (emilokan)
Wo Emi lo ye (emilokan)
Mi o fe fi gbogbo enu soro (emilokan)
Ko ma ti mi mo koro (emilokan)
A mo yan l abuja (emilokan)

2t ma Lu Lu oma dun (emilokan)
To ba ti dun ode ma dun (emilokan).

  • Written by: Qdot
  • Album: Emi Lo Kan
  • Released: 2022
  • Official Video:

Leave a Response