Lyrics

MohBad – Beast & Peace Lyrics

MohBad Beast & Peace Lyrics, MohBad Beast and Peace Lyrics

(The winds will come)
(To steal the words I say) Imole ahn

Ahn, I am on silent mood, but beast ní mí
Mo le cause violence but still, peace ní mí
You don’t have to hurt me, before you win
You don’t have to kill somebody before you sin

O ṣa le browse, lai dẹ lo sub oh
O dẹ le go far without God oh
So, mo duro t’Oluwa
So, ko ki n ṣe iru wa
Even t’ọn ba fun yin labọ pẹlu spoon, ẹ le j’oju wa

Emi ma dẹ ti bad, lati aye ladiladi
Lati aye 1990 t’ọn lu beat patipati
Emi ti mo feel bad, mo dẹ ti feel good
Now, mo feel better, Surulere bi Ojuelegba
Tori pe mo wọ nnkan, wọn sọ pe mo wa on drug
Now, mo wa on top, life mi o dẹ ni contour
Mo pa wọn ni Naija, o tun ba wọn ni London
Fun wọn ni KPK pọ wọn ni Ice Boy wo, mo n tanna
(Light-Boy mo n tanna)

Uh, mummy mi ati daddy mi, wọn kan lọ n question mi
Wọn ni, “Ibo lo ti ri vibe yii, ṣe ọwọ demon?”
Awọn t’ọn senior mi, wọn beere, “Where you see money?”
Awọn ti mo julọ, wọn photocopy mi
First cashout mi, ọmọ’ya, mo dẹ fi ra Bazooka
Mo ko f’awọn sharp shooter
Ẹ ma binu t’ọn ba da a si’ta
Tra-ta-ta-ta-ta-ta fún awọn fake n****

Awọn to fẹ shame mi
Wo, emi wa shameless
Wọn fẹ stain white mi, but mo wa stainless
Awọn n**** t’ọn leave mi, wọn o le ri realness
Tori pe silence mi, no mean say na weakness
Shoutout si Iba J, Diarra pẹlu Hayan
CY, Darosha, Prime Boy
Spending is my daddy, life mi wa splendid
Ologo, Zomo, TIA, Bella

(Chukwuchilly)
Soul
Mi ṣa a mọ
Wọn ni iru ẹ
Iru ẹ t’ọn ni, ko ki n ṣe original
(Boombah)
O fẹ, o fẹ sunmọ mi
But, ko ki n ṣe oun gan-an gan-an